Jump to content

Àgbánréré

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àgbánréré
Temporal range: Eocene–Present
A Black rhinoceros (Diceros bicornis) at the Saint Louis Zoo.
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ]
Ìjọba: Animalia (Àwọn ẹranko)
Ará: Chordata
Ẹgbẹ́: Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ)
Ìtò: Perissodactyla
Superfamily: Rhinocerotoidea
Ìdílé: Àgbánréré
Owen, 1845
Extant and subfossil genera

Ceratotherium
Dicerorhinus
Diceros
Àgbánréré
Coelodonta
Stephanorhinus
Elasmotherium
Fossil genera, see text

Rhinoceros range

Àgbánréré ni ìkan nñú irú-ẹ̀dá márùún oníka-tóṣẹ́kù ẹlẹ́sẹ̀ pátákówà láyé nínú ìdílé Irúẹ̀dá-Àgbánréré (Rhinocerotidae), àti àwọn irú-ẹ̀dá yìówù tó jọ wọ́n sùgbọ́n tí wọn kò sí láyé mọ́. Méjì nínú àwọn irú-èdà tó wà láyé wà ní Áfríkà, mẹ́ta sì wà ní Apágúúsù Asia.