Jump to content

Pepsi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìgo ọtí ẹlẹ́rìndòdò Pepsi, ní ọjà
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the beverage. Fún its manufacturer, ẹ wo: PepsiCo. Fún other uses, ẹ wo: Pepsi (disambiguation).

Àdàkọ:Use mdy dates Àdàkọ:Infobox drink Pepsi jẹ́ ọtí ẹlẹ́rì-dòdò tí ilé-iṣẹ́ PepsiCo ṣe. Ọ̀gbẹ́ni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Caleb Bradham ni ó kọ́kọ́ ṣẹ̀dá rẹ̀ lọ́dún 1893, tí ó sìn pè é nígbà náà ní Brad's Drink, lẹ́yìn èyí ni wọ́n yí orúkọ rẹ̀ sí Pepsi-Cola lọ́dún 1898, [1] tí wọ́n wá ń pè é lápèkúrú ní Pepsi lọ́dún 1962.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named store