Àwòdì
Ìrísí
Àwòdì
Òwe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- A kì í fini joyè àwòdì ká má lè gbádìẹ.
- A kì í du orí olórí kí àwòdì gbé tẹni læ.
- Ìlérí adìẹ, asán ni lójú àwòdì.
- Iṣu àtẹnumọ́ kì í jóná; ọ̀kà àtẹnumọ́ kì í mẹrẹ; àwòdì kì í gbé adìẹ à-tẹnu-kunkun-mọ́.
Pẹ̀lú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Àwòdì apẹja (Pandion haliaetus)
- Èékán-àwòdì (Capparis brassii)