Manuel Dorrego
Manuel Dorrego | |
---|---|
Interim Gómìnà Buenos Aires Province | |
In office 29 June 1820 – 20 September 1820 | |
Asíwájú | Miguel Estanislao Soler |
Arọ́pò | Martín Rodríguez |
Gómìnà Buenos Aires Province | |
In office 13 August 1827 – 1 December 1828 | |
Asíwájú | Juan Gregorio de Las Heras |
Arọ́pò | Juan Lavalle |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 11 June 1787 Buenos Aires, Viceroyalty of the Río de la Plata, Spanish Empire |
Aláìsí | 12 December 1828 Navarro, United Provinces of the Río de la Plata | (ọmọ ọdún 41)
Resting place | La Recoleta Cemetery |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Argentina |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Federal |
Alma mater | Real Universidad de San Felipe |
Profession | Military |
Military service | |
Allegiance | United Provinces of the Río de la Plata |
Unit | Army of the North |
Battles/wars | Second Upper Peru campaign |
Manuel Dorrego (11 June 1787 – 13 December 1828) je ara orile-ede Argentina ati ọmọ-ólógun. Ó jẹ́ Gómìnà Buenos Aires ní ọdún 1820, tí wón sì yan sipo lekansi laarin ọdún 1827 si 1828.
Ìgbésíayé àti òṣèlú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dorrego ni wón bí si Buenos Aires ni ọjọ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 1787 sí ìdílé José Antonio do Rego, ati María de la Ascensión Salas. Ó bẹ̀rẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ Real Colegio de San Carlos ní ọdún 1803, ti o si kuro lọ síReal Universidad de San Felipe ni Captaincy General of Chile lati keko rẹ lọ.[1]
O kó kúrò lọ sí United Provinces of the Río de la Plata (tí wón pe ni Argentina lóde òní), ti o si dárapọ̀ mọn Army of the North, lábẹ asẹ Manuel Belgrano. Ó jà níbi awọn ogun Tucumán ati Salta, tí ò sìse loju ogun mejeji.[1]
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |