Jump to content

Santiago Derqui

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Santiago Derqui
4th Aarẹ orile-èdè Argentina
In office
March 5, 1860 – November 4, 1861
Vice PresidentJuan E. Pedernera
AsíwájúJusto José de Urquiza
Arọ́pòJuan E. Pedernera
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1809-06-21)Oṣù Kẹfà 21, 1809
Córdoba
AláìsíNovember 5, 1867(1867-11-05) (ọmọ ọdún 58)
Corrientes
Ọmọorílẹ̀-èdèArgentine
Ẹgbẹ́ olóṣèlúFederalist

Santiago Rafael Luis Manuel José María Derqui Rodríguez (Córdoba June 21, 1809 – November 5, 1867) je Aare orile-ede Argentina tele.

Àkọ́bíkunrin Manuel José María Derqui y Garcia ati ìyàwó rè Ramona Rodriguez y Ordun̄a, Santiago Derqui kàwé ni Córdoba National University, ó gba àmì ẹyẹ nínú fásitì na agbejoro ni ọdún 1831. Ni ojó kẹrinla oṣù kàrún, ọdún 1845, ó fẹ́ Modesta García de Cossio y Vedoya García (1825–1885) tí o si bi ọmọkunrin méta fún (Manuel Santiago, Simón, and Santiago Martín Antonio) ati ọmọbìnrin méta (Josefa, Justa Dolores Belisaria, and María del Carmen Modesta Leonor).

Ohun ni oluranlowo àkọ́kọ́ ati mínísítà ìjọba ti Corrientes Province lábẹ José María Paz. Justo José de Urquiza fún ni 'Business administrator' tí o si ran lọ sí Paraguay fún iṣẹ ilu orile-èdè miran.[1]


  1. "Masones Ilustres Argentinos". Archived from the original on 2013-09-22. Retrieved 2013-04-02.