Jump to content

Kànnáfùrù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Clove
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Ìjọba: Ọ̀gbìn
Irú:
Plantae
Ìfúnlórúkọ méjì
Plantae
Synonyms[1]
  • Caryophyllus aromaticus L.
  • Eugenia aromatica (L.) Baill.
  • Eugenia caryophyllata Thunb.
  • Eugenia caryophyllus (Spreng.) Bullock & S.G.Harrison
  • Jambosa caryophyllus (Thunb.) Nied.

Kànnáfùrù jẹ́ ìran igi ewé kan tí ó wá láti inú ẹbí igi kan tí wọ́n ń pe ní Myrtaceae, tí orúkọ àdàmọ̀dì rẹ̀ ń jẹ́ Syzygium aromaticum ( /sɪˈzɪəm ˌærəˈmætɪkəm/).[2][3] Ìlú tí ewé yí ti tàn ká agbáyé ni Maluku Islands, tí a tún lè pè ní Moluccas, ìlú tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Indonesia. Won ma ń lo ewé tàbí igi kànáfùrù yí fún oríṣiríṣi ìwúlò ọmọnìyàn, wọ́n lè loo gẹ́gẹ́ bí ohun èlò amọ́bẹ̀ dùn, ohun olóòrùn àdídùn tàbí kí wọ́n fi kún ọṣẹ ifọ̀yín àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[4][5] èso tàbí igi kànáfùrù ma ń so yíká ọdún yálà lásìkò ẹ̀rùn ni tàbí àsìkò òjò, idi nìyí tí a ṣe ma ń ri káàkiri orílẹ̀ agbáyé yàtọ̀ sí àwọn irúgbìn tókù.[6]

Dried cloves
Clove tree flowerbuds

Àdàkọ:Cookbook

Wọ́n ma ń lo kànáfùrù gẹ́gẹ́ bí nkan ìsebẹ̀ tàbí gẹ́gẹ́ bí ohun amọ́bẹ̀ ta sánsán ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ ati ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀ káàkiri agbáyé.

Wọ́n lè lo kànáfùrù fún ohun mímu ẹlẹ́rìndòdò nígbà tí wọ́n bá fi mọ́ ṣúgà àti ọsàn òronbó.[7]) àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Lílò rẹ̀ fún nkan mìíràn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n ma ń fi kànáfùrù kún èso betel quids kí ó lè mú òórùn àdídùn wá nígbà tí wọ́n bá ń jẹẹ́.[8] Wọ́n tún ma ń fi kànáfùrù kún egbògi táábà tí wọ́n fi ń ṣe sìgá tí wọ́n ń pe ní kretek ní orílẹ̀-èdè Indonesia.[1] Àwọn ènìyàn olùgbé àwọn ìlú bíi Europe, Asia àti Amẹ́ríkà ni wọ́n sábà ma ń mu sígá tí wọ́n fi Kànáfùrù ṣe lọ́pọ̀lọp [9] látàrí ìfòfinde awọn sìgá tí wọ́n táábà olóró ṣe jáde ní awọn ìlú wọ̀nyí ní inú oṣù kẹsànán ọdún 2009.[10]

Wọ́n lè lo Òróró kànáfùrù láti dáàbò bo oúnjẹ kúrò lọ́wọ́ onírúurú àwọn ìfúnfun tí wọ́n wọ́n ma ń ju lórí àwọn oúnjẹ. [11] Wọ́n tún ma ń fi òróró kànáfùrù ṣe itọ́jú oúnjẹ kí ó má ba bàjẹ́, bákan náà ni wọ́n ma ń loo fún ìdáàbò bo igi kúrò lọ́wọ́ àwọn kòkòrò ajẹgirun.[12] Won le lo kànáfùrù láti fi ṣe ohun olóòórùn àdídùn sínú ilé nígbà tí wọ́n bá pa á pọ̀ mọ́ ọsàn mímu.

Cloves drying in sun


Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 Àdàkọ:GRIN
  2. Àdàkọ:Cite OED
  3. Àdàkọ:Cite Merriam-Webster
  4. "Syzygium aromaticum (L.) Merr. and L.M. Perry". Kew Science, Plants of the World Online. 2021. Retrieved 28 February 2021. 
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named drugs
  6. Yun, Wonjung (13 August 2018). "Tight Stocks of Quality Cloves Lead to a Price Surge". Tridge. https://www.tridge.com/stories/tridge-market-update-tight-stocks-of-quality-cloves-lead-to-a-price-surge. 
  7. Hariati Azizan (Aug 2, 2015). "A spicy blend of tradition". The Star: p. 9. 
  8. Rooney, Dawn F. (1993). Betel Chewing Traditions in South-East Asia. Kuala Lumpur: Oxford University Press. p. 26. ISBN 0-19-588620-8. 
  9. "Flavored Tobacco". FDA. Retrieved September 7, 2012. 
  10. "The Tobacco Control Act's Ban of Clove Cigarettes and the WTO: A Detailed Analysis" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Congressional Research Service Reports. 17 September 2012. Retrieved 2022-05-12. 
  11. Ju, Jian; Xu, Xiaomiao; Xie, Yunfei; Guo, Yahui; Cheng, Yuliang; Qian, He; Yao, Weirong (2018). "Inhibitory effects of cinnamon and clove essential oils on mold growth on baked foods" (in en). Food Chemistry 240: 850–855. doi:10.1016/j.foodchem.2017.07.120. PMID 28946351. https://linkinghub.elsevier.com/retrieve/pii/S0308814617312736. 
  12. Pop, Dana-Mihaela; Timar, Maria Cristina; Varodi, Anca Maria; Beldean, Emanuela Carmen (December 2021). "An evaluation of clove (Eugenia caryophyllata) essential oil as a potential alternative antifungal wood protection system for cultural heritage conservation" (in en). Maderas. Ciencia y tecnología 24. doi:10.4067/S0718-221X2022000100411. ISSN 0718-221X. http://www.scielo.cl/scielo.php?script=sci_arttext&pid=S0718-221X2022000100411&lng=es&nrm=iso&tlng=es.