Jump to content

John Pepper Clark

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
EK, BA ati JP Clark
John Pepper Clark
J. P. Clark
Ọjọ́ìbíJohn Pepper Clark-Bekederemo
(1935-04-06)6 Oṣù Kẹrin 1935
Kiagbodo, Delta, Nigeria
Aláìsí13 October 2020(2020-10-13) (ọmọ ọdún 85)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànJohn Pepper Clark
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ibadan
Iṣẹ́Poet, playwright
Notable workA Decade of Tongues
AwardsNigerian National Order of Merit Award

John Pepper Clark-Bekederemo (ojoibi April 6, 1935 tosi ku ni ọjọ mẹtala óṣu October ọdun 2020) je olukowe omo ile Naijiria. Arakunrin naa ni órukọ rẹ ma njade nigba toba kọ iwè gẹgẹbi J.P. Clark ati John Pepper Clark[1][2].

Igbesi Ayè Arakunrin naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

John ni a bisi Kiagbodo,ilú naigiria fun Baba rẹ to jẹ ọmọ ilè Ijaw ati Iya rẹ to jẹ ọmọ ilẹ Urhobo. Nigba ti arakunrin naa jade lati ilè iwè giga ti Ibadan ni ó ṣiṣẹ gẹ̀gẹbi Officer ti Information ni ministry ti information ati research fellow ni Institute ti imọ ẹkọ ilẹ Africa ni ilè iwè giga ti Ibadan[3][4].

Ni ọdun 1982, John ati Iyawó rẹ Ẹbun Odutola (Professor ati óludari tẹlẹ ri) da theatre ti PEC Repertory silẹ ni ilú eko[5].

Clark ku si ilè iwosan to wa ni eko ni ọjọ kẹkatala óṣu October ni ọdun 2020[6].

Clark lọsi ilè iwè Native Authority ni Okrika ni ijọba ibilẹ ti Burutu, ilè iwè ti Ijọba ni Ughelli lẹyin ló tẹsiwaju lọsi ilè iwè giga ti Ilú Ibadan lati kẹẹkọ lọri imọ ede gẹẹsi. Arakunrin naa fun aimoyè ọdun lóti jẹ professor ti èèdè gẹẹsi ni ilè iwè giga ti Eko to si fẹyinti ni ọdun 1980. Clark tigba ipó professor ni ilè iwè giga ti Yale ati Wesleyan ni ilú United States[7][8].

J.P Clark Center,University of Lagos

Ami Ẹyẹ ati Idanilọla

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Clark gba Ami Ẹyẹ ti National Order of merit ti ilẹ naigiria lati ọdọ ilè iwè giga ti Howard lóri iwè rẹ "The ozidi Saga ati Akójọpọ Ere ati Ewi lati ọdun 1958-1988[9].

Ni ọjọ kẹfa, óṣu December ni ọdun 2011 ni ayẹ Ayè Professor John Pepper Clark pẹlú ayẹyẹ to waye ni Ikoyi[10]. Ni ọdun 2015 ni Awọn ọdọ ólukọwè ti ilẹ naigiria labẹ akoso Wole Adedoyin da ẹgbẹ JP clark ti Literay lati igbè iṣẹ Clark larugẹ[11][12].