Jump to content

Almaty

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Almaty, Kazakhstan.
Almaty

Алматы
Flag of Almaty
Flag
Official seal of Almaty
Seal
Country Kazakhstan
First settled10th-9th century BC
Founded1854
Incorporated (city)1867
Government
 • Akim (mayor)Bauyrzhan Baybek
Area
 • Total324.8 km2 (125.4 sq mi)
Elevation
500 - 1,700 m (1,640 - 5,577 ft)
Population
 (2009)
 • Total1,420,747
 • Density4,152/km2 (10,750/sq mi)
Time zoneUTC+6 (UTC+6)
Postal code
050000 - 050063
Area code(s)+7 727[1]
ISO 3166-2ALA
License plateA
Websitehttp://www.almaty.kz

Almaty (Àdàkọ:Lang-kz), tele gege bi Alma-Ata (Rọ́síà: [Алма-Ата] error: {{lang}}: text has italic markup (help), titi 1992) ati bakanna bi Verny (Russian: Верный, tit 1921), ni ilu titobijulo ni orile-ede Kazakhstan, pelu iye eniyan to to 1,348,500 (ni 1 September 2008),[2] eyi duro fun 9% iye gbogbo eniyan orile-ede na.

O ti je oluilu Kazakhstan (ati ti Kazakh SSR tele) lati 1929 titi di 1997. Botilejepe kii se oluilu Kazakhstan mo sibesibe Almaty si je ilu isowo pataki ni Kazakhstan.

  1. "CODE OF ACCESS". Archived from the original on 2014-08-14. Retrieved 2009-12-21. 
  2. "«Almaty population as of September 1, 2008 made 1 million 348.5 thousand people»" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 20 May 2011. Retrieved 14 November 2008.