Wikipedia:Àwọn lẹ́tà Yorùbá
Lẹ́tà Àpilẹ̀kọ Yorùbá jẹ́ ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ kan pàtàkì tí a fi ma ń bá ẹni tó wà lọ́nà jíjìn sọ̀rọ̀, yálà lóri ohun tó ṣe kókó lórí ònkọ̀wé tàbí lórí ayé ẹni tí a kọọ́ sí. lẹ́tà tún jẹ́ ọ̀rọ̀ àṣírí tí a kọ pamọ́, tí a fi èdè Yorùbá ṣe lọ́jọ̀, gbé kalẹ̀, fún àgbọ́yé ẹni tí ó gbọ́ èdè Yorùbá tí a fi gbé lẹ́tà náà kalẹ̀.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn létà Alifabeeti ede Yorùbá ni : LETA NLÁ : A B D E Ẹ F G GB H I J K L M N O Ọ P R S Ṣ T U W Y . Létà Kékeré : a b d e ẹ f g gb h i j k l m n o ọ p r s ṣ t u w y . Ọnà meji pàtàkì ni a lè pín awọn leta wonyii sí. (1) IRO KONSONANTI ( CONSONANT SOUNDS).AWON NI: B D F G GB H J K L M N P R S Ṣ T W Y. A tún lẹ̀ pín awọn irọ wonyìí sí ọna meji báyìí (a) Konsonanti Airanmupe : b d f g gb h j k l p r s ṣ t w y. (b) Konsonanti Aranmupe : m ati n. (2) IRO FAWÉLI ( vowel sounds ) Awọn ni : A E Ẹ I O Ọ U . A le pin faweli náà sí ọna meji bayii (1) Faweli Airanmupè . Awọn ni : A E Ẹ I O Ọ U . (11) Faweli Aranmupe . Awon ni : AN ẸN IN ỌN UN
- ↑ Kone, Moussa (2018-04-19). "Yorùbá Publishing Manual". Orisha Image. Retrieved 2019-01-11.