Srinivasa Ramanujan
Srinivasa Ramanujan | |
---|---|
Ìbí | Erode, British India | 22 Oṣù Kejìlá 1887
Aláìsí | 26 April 1920 Chetput, (Madras), British India | (ọmọ ọdún 32)
Ibùgbé | Tamil Nadu, India |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Indian |
Pápá | Mathematics |
Ibi ẹ̀kọ́ | Government Arts College Pachaiyappa's College Cambridge University |
Academic advisors | G. H. Hardy J. E. Littlewood |
Ó gbajúmọ̀ fún | Landau–Ramanujan constant Mock theta functions Ramanujan conjecture Ramanujan prime Ramanujan–Soldner constant Ramanujan theta function Ramanujan's sum Rogers–Ramanujan identities |
|
|||||
Problems listening to this file? See media help. |
Srīnivāsa Aiyangār Rāmānujam FRS, daada bi Srinivasa Iyengar Ramanujan ipejade (ìrànwọ́·ìkéde) (Tàmil: சீனிவாச இராமானுஜன் or ஸ்ரீனிவாஸ ஐயங்கார் ராமானுஜன்) (22 December 1887 – 26 April 1920) je ara India olusemathimatiki ati akekofunraeni to, lai gba eko alagbese kankan ninu mathimatiki ogidi, ko ipa pataki si ituwo onimathimatiki, iro nomba, awon eseese alailopin ati awon ida aromoniso. Talenti Ramanujan je siso, latowo eni pataki olusemathimatiki ara Ilegeesi G.H. Hardy, pe o wa niduro kanna bi ti awon olusemathimatiki bi Euler, Gauss, Newton ati Archimedes [1].
A bi ni Erode, Tamil Nadu, India, Ramanujan koko pade mathimatiki alagbese nigba to to omo odun 10. O fi ebun re ori re han, won si fun ni awon iwe lori trigonometry agbega ti S. L. Loney ko.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ C.P. Snow Foreword to "A Mathematician's Apology" by G.H. Hardy
- ↑ Berndt, Bruce C. (2001). Ramanujan: Essays and Surveys. Providence, Rhode Island: American Mathematical Society. pp. 9. ISBN 0-8218-2624-7.