Sam Cooke
Ìrísí
Sam Cooke | |
---|---|
Sam Cooke in studio, 1963 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Samuel Cook[1] |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Dale Cooke |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Chicago, Illinois, U.S. |
Irú orin | R&B, soul, gospel, pop |
Occupation(s) | Singer-songwriter, entrepreneur |
Instruments | Vocals, piano, guitar |
Years active | 1950–1964 |
Labels | Specialty, Keen, RCA |
Associated acts | The Soul Stirrers Bobby Womack Johnnie Taylor |
Samuel Cook[1] (January 22, 1931 – December 11, 1964), to gbajumo bi Sam Cooke, je akorin gospel, R&B, soul, ati pop ara Amerika, akorin, ati onisowo. O je gbigba bi ikan ninu awon asiwaju ati oludasile orin soul.[2] Wo unpe bi Oba Orin Soul fun iru ohun ikorin re ati ipa to ni lori orin agbaye odeoni. Ipa re lori Orin Soul lo fa idide Aretha Franklin, Bobby Womack, Curtis Mayfield, Stevie Wonder, Marvin Gaye, o si je ki awon akorin bi Otis Redding ati James Brown o gbajumo.[3][4][5]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Sam Cooke". Britannica online. Retrieved 2008-09-28.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedpc17
- ↑ Appiah, Kwame Anthony; Gates, Henry Louis; Gates, Henry Louis, Jr. (2004). Africana: An A-to-Z Reference of Writers, Musicians, and Artists of the African American Experience. Running Press. p. 146. ISBN 0-762-42042-1.
- ↑ DeCurtis, Anthony; Henke, James (1992). The Rolling Stone Illustrated History of Rock & Roll: The Definitive History of the Most Important Artists and their Music. George-Warren, Holly. Random House. p. 135. ISBN 0-679-73728-6.
- ↑ Nite, Norm N. (1992). Rock On Almanac: The First Four Decades of Rock 'n' Roll: A Chronolology. New York, New York: HarperPerennial. pp. 140–142.