Hope Waddell Training Institute
Ìrísí
Hope Waddell Training Institution | |
---|---|
Fáìlì:Hope Wadell Logo.jpg | |
Motto | In Spe Gloria Dei ("In hope of the glory of God") |
Established | 1895 |
Type | Secondary |
Location | Calabar, Cross River State, Nigeria |
Hope Waddell Training Institution (HOWAD) jẹ́ ilé-ìwé ẹ̀kọ́ṣẹ́ tí ó fìkàlẹ̀ sí ìlú Calabar, ní Ìpínlẹ̀ Cross River, lórílẹ̀-èdè Nigeria. Àwọn àlùfáà ìjọ kìrìsìtẹ́nì ti United Presbyterian Church of Scotland ni wọ́n dá a sílẹ̀ lọ́dún 1895, tí wọ́n sì só lorúkọ àlùfáà ìjọ náà nígbà náà Hope Masterton Waddell.[1]
Àwọn ọ̀gá-àgbà ilé-ìwé náà láti ìbẹ̀rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn wọ̀nyí ni ọ̀gá-àgbà ilé-ìwé náà títí di ọdún 1960 síwáju:[2]
ọ̀gá-àgbà ilé-ìwé | Ẹ̀yà | ọdún |
---|---|---|
W.R. Thompson | ọmọ orílè-èdè Scotland | 1895 - 1902 |
James Luke | ọmọ orílè-èdè Scotland | 1902 - 07 |
J.K. Macgregor | ọmọ orílè-èdè Scotland | 1907 - 43 |
E. B. Jones | ọmọ orílè-èdè Scotland | 1943 - 45 |
N. C. Macrae | ọmọ orílè-èdè Scotland | 1945 - 52 |
J. A. T. Beattie | ọmọ orílè-èdè Scotland | 1952 - 57 |
Sir Dr. Francis Akanu Ibiam | ọmọ Ìgbò | 1957 - 60 |
B. E. Okon | ọmọ Efik | 1960 - 74 |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Archibong 2005.
- ↑ Taylor 1996, pp. 265.