Harriet Tubman
Ìrísí
Harriet Tubman | |
---|---|
Harriet Tubman c. 1880 | |
Ọjọ́ìbí | 1820 Dorchester County, Maryland |
Aláìsí | Auburn, New York | Oṣù Kẹta 10, 1913
Olólùfẹ́ | John Tubman, Nelson Davies |
Parent(s) | Ben and Harriet Greene Ross |
Harriet Tubman (abiso Araminta Ross; c. 1820 or 1821 – March 10, 1913) je omo Afrika Amerika to je olutudekun, aseteyan, ati oluwona nigba Ogun Abele Amerika. Leyin igba to sa kuro ni oko eru, nibi ti won bi si, o se iranlose metala lati se itusile awon eru bi 70[1] nipa lilo awon eto ati ile abo awon alakitiyan alodioko eru ti a mo si Underground Railroad. Lojo waju o ran John Brown lowo lati wa awon eniyan ti won rolu Harpers Ferry ni, o si tun sakitiyan fun eto ibo awon obinrin.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Larson, p. xvii.