Jump to content

HTML

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
HTML
(HyperText Markup Language)
Filename extension.html, .htm
Internet media typetext/html
Type codeTEXT
Uniform Type Identifierpublic.html
Developed byWorld Wide Web Consortium & WHATWG
Type of formatMarkup language
Extended fromSGML
Extended toXHTML
Standard(s)ISO/IEC 15445
W3C HTML 4.01
W3C HTML 5 (draft)
Àpẹrẹ àmìọ̀rọ̀ HTML

HTML to duro fun HyperText Markup Language je opagun kariaye.

HTML je akanda ede Pataki ti a n lo lati ko webu ni pele n pele.

HTML ni orisirisi eroja ti a le lo lati we abi bo awon ara eya ara oun ti  o wa ninu webu lati je ki o ri bi a se fe ki o ri. Fun apeere, a le lo lati je ki oro inu webu ko tobi abi ko kere abi lati kun ni orisirisi oda bi oda eweko, oda fun, abi dudu abi pupa. A tun le lo HTML lati je ki awon aworan, fidio ati oro ti o wa ninu webu ki o dun nwo loju nipa mimu ki o tobi tabi kere, tabi ki o tan yinyin tabi ki o dudu.

A le fi Jafa ati CSSS kun HTML lati jeki webu ko ni iwulo pupo ati ko le dun now loju si. Ti a ba fi CSSS kun HTML, a le yipada abi se atunse abi afikun bi webu se ma ri ti yo fi rewa ti yoo dun n wo loju. Ti a ba fi Jafa kun HTML, a o le e fi awon iwulo pupo kun webu wa. Fun apere, ti eniyan kan ba fi owo kan botini kan ni inu webu, opolopo n kan ti awon onimo ise ayarabi-asa fi si ori webu lo le yi pada si bi won se se eto re sibe.[1]



  1. Mozilla.org. (2023). HTML basics - Learn web development | MDN. [online] Available at: https://developer.mozilla.org/en-US/docs/Learn/Getting_started_with_the_web/HTML_basics [Accessed 22 Oct. 2023]. ‌