Jump to content

Donna Reed

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use American English Àdàkọ:Use mdy dates

Donna Reed
Donna Reed in the 1950s
Ọjọ́ìbíDonna Belle Mullenger
(1921-01-27)Oṣù Kínní 27, 1921
Denison, Iowa, U.S.
AláìsíJanuary 14, 1986(1986-01-14) (ọmọ ọdún 64)
Beverly Hills, California, U.S.
Resting placeWestwood Village Memorial Park Cemetery
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1941–1986
Olólùfẹ́
William J. Tuttle
(m. 1943; div. 1945)

Tony Owen
(m. 1945; div. 1971)

Grover Asmus
(m. 1974)
Àwọn ọmọ4

Donna Reed (wọ́n bí Donna Belle Mullenger; ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kìíní , ọdún 1921 – ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìnlá, oṣù kìíní, ọdún 1986) ó jẹ́ òṣèrè Amẹ́ríkà. Ìgbà tó fi ṣe eré lọ fún bíi ogójì , pẹ̀lú àwọn ipa àti akitiyan rẹ̀ ní fíìmù tó ju ogójì lọ. Àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́ dáadáa fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Mary Hatch Bailey ní eré Frank Capra tó pè ní fantasy holiday film It's a Wonderful Life (1946). Reed gba Academy Award for Best Supporting Actress fún Fred Zinnemann's war fíìmù From Here to Eternity (1953).

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Reed sí Donna Belle Mullenger ni oko lẹ́ẹ̀gbẹ́ Denison, Iowa, ó jẹ́ ọmọbìnrin fún Hazel Jane (tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Shives) àti William Richard Mullenger.[1] òun ló dàgbà jù láàárín àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òbí ẹ̀ bí, wọ́n tó dàgbà bíi mẹ́dọ́dìsì.[2] Ní ọdún 1936, nígbà tó wà ní kíláàsì tó kàn kó tó parí ìwé-ilé rẹ̀ ní Denison (Iowa) , kẹ́mísítírí tisà rẹ̀ fún un ní How to Win Friends and Influence People. Ìwé náà jẹ́ ìwé to yìí ayé ẹ̀ padà sí dáadáa . Lẹ́yìn tó kà á tán, ó gba òṣèrè àkọ́kọ́ ní eré tó ṣe ní ilé-ìwé rẹ̀, wọ́n tún dìbò fún un ní ilé-ìwé rẹ̀ fún olorì wọn àti wí pé ó wà ní àwọn mẹ́wàá àkọ́kọ́ tó ṣe tán ní ọdún 1938 ní ilé-ìwé náà. Tompkins bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣíṣe lórí Manhattan Project.[3]

Lẹ́yìn to parí ìwé ẹ̀ tàn-ná ní Denison, Reed lérò láti di olùkọ́ ṣùgbọ́n kò rówó san fún fásitìto. Nígbà náà lo padà lọ sí kalifónáì tó lọ sí ilé-ìwé Los Angeles City College ní ìmọ̀ràn ààntí rẹ̀. Nígbà tó wà ní Fásitì, ó ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré orí-ìtàgé, àmọ́ nígbà náà kò tì í ni lọ́kàn láti di Òṣèrè. Lẹ́yìn tí ọ̀pọ̀ àwọn pè é tó dárapọ̀ mọ́ àwọn ni ó padà darapọ̀ mọ́ screen test ní sítúdíò wọn, Reed tọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú Metro-Goldwyn-Mayer; Lẹ́yìn ìgbà náà, in pinnu láti parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ tan náà.[4][5] Ó parí ẹ̀kọ́ Fásitì rẹ̀, lẹ́yìn náà ló tọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ agent.[6]

Year Title Role Notes
1947 Lux Radio Theatre Episode: It's A Wonderful Life
1948 Lux Radio Theatre Episode: You Were Meant For Me
1949 Lux Radio Theatre Episode: High Barbaree
1949 Lux Radio Theatre Episode: Deep Waters
1951 Lux Radio Theatre Episode: To Please A Lady
1952 Screen Guild Theater Episode: The Mating of Millie[7]
1954 Lux Radio Theatre Episode: The Naked Jungle
1955 Lux Radio Theatre Episode: Rawhide
Year Title Role Notes
1940 Convicted Woman Inmate Uncredited
1941 The Get-Away Maria Theresa 'Terry' O'Reilly
1941 Shadow of the Thin Man Molly
1941 Babes on Broadway Jonesy's Secretary Uncredited
1942 The Bugle Sounds Sally Hanson
1942 The Courtship of Andy Hardy Melodie Eunice Nesbit
1942 Mokey Anthea Delano
1942 Calling Dr. Gillespie Marcia Bradburn
1942 Apache Trail Rosalia Martinez
1942 Eyes in the Night Barbara Lawry
1942 Personalities Uncredited
1943 The Human Comedy Bess Macauley
1943 Dr. Gillespie's Criminal Case Marcia Bradburn Alternative title: Crazy to Kill
1943 The Man from Down Under Mary Wilson
1943 Thousands Cheer Customer in Red Skelton Skit
1944 See Here, Private Hargrove Carol Holliday
1944 Gentle Annie Mary Lingen
1945 The Picture of Dorian Gray Gladys Hallward
1945 They Were Expendable Lt. Sandy Davyss
1946 Faithful in My Fashion Jean Kendrick
1946 It's a Wonderful Life Mary Hatch Bailey
1947 Green Dolphin Street Marguerite Patourel
1948 Beyond Glory Ann Daniels
1949 Chicago Deadline Rosita Jean D'Ur
1951 Saturday's Hero Melissa Alternative title: Idols in the Dust
1952 Scandal Sheet Julie Allison Alternative title: The Dark Page
1952 Rainbow 'Round My Shoulder Herself Uncredited
1952 Hangman's Knot Molly Hull
1953 Trouble Along the Way Alice Singleton Alternative title: Alma Mater
1953 Raiders of the Seven Seas Alida
1953 From Here to Eternity Alma "Lorene" Burke Academy Award for Best Supporting Actress
1953 The Caddy Kathy Taylor
1953 Gun Fury Jennifer Ballard
1954 They Rode West Laurie MacKaye
1954 Three Hours to Kill Laurie Mastin
1954 The Last Time I Saw Paris Marion Ellswirth / Matine
1955 The Far Horizons Sacajawea Alternative title: The Untamed West
1956 The Benny Goodman Story Alice Hammond
1956 Ransom! Edith Stannard Alternative title: Fearful Decision
1956 Backlash Karyl Orton
1956 Beyond Mombasa Ann Wilson
1958 The Whole Truth Carol Poulton
1960 Pepe Herself (cameo)
1979 The Best Place to Be Sheila Callahan TV movie
1983 Deadly Lessons Miss Wade TV movie

Àwọn Àwọ́ọ̀dù àti àwọn ibi tó wọn tí yànnọ́ fún Àwọ́ọ̀dù

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Year Award Category Title Result
1953 Academy Awards Best Supporting Actress From Here to Eternity Gbàá
1964 Bravo Otto Best Female TV Star The Donna Reed Show| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
1964 Golden Apple Awards Most Cooperative Actress Gbàá
1963 Golden Globe Awards Best TV Star – Female The Donna Reed Show Gbàá
2006 Online Film & Television Association Television Hall of Fame: Acting Gbàá
1959 Primetime Emmy Awards Best Actress in a Leading Role (Continuing Character) in a Comedy Series| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
1960 Outstanding Performance by an Actress in a Series (Lead or Support)| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
1961 Outstanding Performance by an Actress in a Series (Lead)| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
1962 Outstanding Continued Performance by an Actress in a Series (Lead)| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
2004 TV Land Awards The Most Irreplaceable Replacement Dallas| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named film-ref
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named drs
  3. "75-year history of Broadway Elementary building celebrated". Denison Bulletin-Review. March 20, 2012. Archived from the original on 2019-12-03. Retrieved April 9, 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Royce 1990, p. 2.
  5. "Donna Reed Says Success and Beauty Depend on Happiness Lane, Lydia". Los Angeles Times: p. C9. Aug 23, 1953. 
  6. Bawden, James; Miller, Ron (2019). Conversations with Legendary Television Stars. Lexington, Kentucky: The University Press of Kentucky. p. 275. ISBN 978-0-8131-7765-6. https://books.google.com/books?id=zS2eDwAAQBAJ&pg=PT275. 
  7. Kirby, Walter (April 13, 1952). "Better Radio Programs for the Week". The Decatur Daily Review. p. 48. https://www.newspapers.com/clip/2394805/decatur_daily_review_april_13_1952/.  open access publication - free to read