Adil Abdul Mahdi
Adil Abdul-Mahdi عادل عبد المهدي | |
---|---|
Adil Abdul-Mahdi in 2008 | |
Prime Minister of Iraq | |
In office 25 October 2018[1] – 7 May 2020 | |
Ààrẹ | Barham Salih |
Deputy | Thamir Ghadhban Fuad Hussein |
Asíwájú | Haider al-Abadi |
Arọ́pò | Mustafa Al-Kadhimi |
Minister of Oil | |
In office 8 September 2014 – 19 July 2016 | |
Alákóso Àgbà | Haider al-Abadi |
Asíwájú | Abdul Karim Luaibi |
Arọ́pò | Jabbar Alluaibi |
Vice President of Iraq | |
In office 7 April 2005 – 11 July 2011 Serving with Ghazi al-Yawer (until 2006) and Tariq al-Hashimi (after 2006) | |
Ààrẹ | Jalal Talabani |
Asíwájú | Rowsch Shaways |
Arọ́pò | Tariq al-Hashimi |
Minister of Finance | |
In office 2 June 2004 – 6 April 2005 | |
Alákóso Àgbà | Ayad Allawi |
Asíwájú | Kamel al-Kilani |
Arọ́pò | Ali Allawi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Adil Abdul-Mahdi al-Muntafiki 1 Oṣù Kínní 1942 Baghdad, Kingdom of Iraq |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent (since 2017)[2] SIIC (1982–2017)[3] Iraqi Communist (1970s)[4] |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Rajah |
Alma mater | University of Baghdad(BA) University of Poitiers (MA, PhD) |
Adil (Adel) Abdul-Mahdi (al Muntafiki) (Lárúbáwá: عادل عبد المهدى ) (ojoibi 1942 ni Baghdad, Iraq) je Shi'a oloselu, onimo oro-okowo ati ikan ninu awon Igbakeji Aare ile Irak meji tele. Teletele o ti je Alakoso Eto Inawo ninu ijoba igbadie.
Ìgbẹ́ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Adil ní ìlú Baghdad ní ọdún 1942. Ó kẹ́kọ́ ní Baghdad College. Ó kẹ́kọ́ nípa ìmọ̀ Economics ní fasiti Baghdad. Adil ṣiṣẹ́ gẹgẹ bí akọ̀wé fun Iraqi foreign Ministry ni ọdún 1965. Ni ọdún 1972, o keko gboye Masters ni fasiti University of Poitiers.
Ikọwe fiposile
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni ojo kokandinlogbon, oṣù kọkànlá ọdún 2019, leyin ọpọlọpọ ifehonuhan, Mahdi sọpé ohun kowe fiposilẹ.[5][6] Aṣòfin Iraqi fọwọ́sí ikowe fiposilẹ rẹ ni ọjọ́ kinni, oṣù Kejìlá ọdún, 2019.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "H.E. Prime Minister Adil Abd Al-Mahdi receives a call from U.S secretary of Defense Mark Esper". www.pmo.iq.
- ↑ Salaheddin, Sinah (3 October 2018). "Iraq tasks Shiite independent with forming new government". Associated Press. Archived from the original on 4 October 2018. Retrieved 16 October 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "عادل عبد المهدي". Al Jazeera.
- ↑ Doug Struck (14 February 2015). "Prospective Iraqi Premier a Man of Many Labels". Washington Post. https://www.washingtonpost.com/wp-dyn/articles/A21745-2005Feb13.html.
- ↑ Iraqi PM says he will resign after weeks of killing protests - Guardian(29 November 2019)
- ↑ Iraq unrest: PM Abdul Mahdi to resign after bloodiest day in protests - BBC(29 December 2019)