Jump to content

Ìjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìjàmbá ìtúká Èbúté Bèírùtù ọdún 2020
Aftermath of the explosions, showing the destroyed grain silo to the left and the flooded blast crater to the right
Map
Date4 Oṣù Kẹjọ 2020 (2020-08-04)
Time18:08:18 EEST (15:08:18 UTC)
(second explosion)
VenuePort of Beirut
LocationBeirut, Lebanon
Coordinates33°54′05″N 35°31′08″E / 33.90139°N 35.51889°E / 33.90139; 35.51889Coordinates: 33°54′05″N 35°31′08″E / 33.90139°N 35.51889°E / 33.90139; 35.51889
TypeAmmonium nitrate explosion
CauseFire
Deaths207+
Non-fatal injuries6,500+
Missing9
Property damageUS$15+ billion
Displaced~300,000

Ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹrin oṣù kẹjọ ọdún 2020, jàmbá iná ló fa ìtúká aláriwo olóró ní èbúté ìlú Bèírùtù, tó jẹ́ olúìlú orílẹ̀-èdè Lẹ́bánọ́nù. Ìtúká aláriwo kejì lágbára tó bẹ́ẹ̀ gẹ́, tó ṣokùnfà ikú àwọn ènìyàn tó pọ̀ tó ẹ̀tà-dín-lẹ́wàá-lé-nígba, àwọn tó farapa tó ẹgbẹ̀fàlélẹ́ẹ̀dẹ́gbẹ̀ta, àwọn ohun ìní tó ṣòfò tó US$10 sí 15 billionu, ìṣẹ̀lẹ̀ náà sọ àwọn ènìyàn tó pọ̀ tó ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀dógún (300,000) di aláìnílé.[1]Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ṣẹlẹ̀ nítorí 2,750 tonnes (3,030 short tons; 2,710 long tons) àmóníọ́mù onínáítirójiínì – tí agbára rẹ̀ tó 1.2 kilotons of TNT (5.0 TJ) – tí ìjọba Lẹ́bánọ́nù ti gbẹ́sẹ̀lé látọwọ́ ọkọ̀ ojú-omi akẹ́rù "MV Rhosus", tí wọ́n sì kó pamọ́ sí apá kan ní èbúté náà láì sí àbò àti ìṣọ́ra tó yẹ fún ọdún mẹ́fà.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Infographic: How big was the Beirut explosion?". Al Jazeera. 2022-08-04. Retrieved 2023-08-30.