Frantz Fanon
Ìrísí
Frantz Fanon | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | 20 July 1925 Fort-de-France (Martinique, France) |
Ọjọ́ aláìsí | 6 December 1961 Bethesda, Maryland |
Spouse | Josie Fanon |
Children | Olivier Fanon Mireille Fanon-Mendès |
Frantz Fanon (July 20, 1925 – December 6, 1961) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Faransé oníwọsàn ààrùn ọpọlọ, amoye, olujidide àti oǹkọ̀wé tí àwọn ìwé rẹ̀ dá lórí àwọn Ẹ̀kọ́ ìgbà eyin imusin, critical theory ati Marxism.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |